Show Overview

2- Alaye lori awon idajo ti o sopo mo irun Jimoh, ninu won ni: (1) Asiko wo ni irun Jimoh maa n wole. (2) Onka wo ni o ye ki o pe ki a to le ki irun Jimoh. (3) Rakah melo ni Musulumi gbodo ba ki o to le gba pe oun ba irun Jimoh.3- Alaye lori wipe Ojise Olohun- ike ati ola Olohun ki o maa ba a maa n gbe ohun soke ni ti o ba n se khutuba ti o si maa n se khutuba ni iduro, gbogbo awon nkan wonyi ni o si maa n se okunfa ki khutuba ni ilapa lara awon ti won n gbo o.4- Oro waye ni apa kerin yi lori Pataki yiyara lo si mosalasi ni ojo Jimoh ati Pataki titeti si Imam ni asiko khutuba, bakannaa ojuse eni ti o ba tete de mosalasi ati eni ti o pe de mosalasi nibi nafila ti a n pe ni "Tahiyyatul-masjid".5- Oro waye ninu apa karun yi lori awon suura ti Ojise Olohun- ike ati ola Olohun ki o maa ba a- maa n ka ninu irun Jimoh ati irun odun mejeeji pelu alaye awon eko ti o wa ninu awon suura naa, oludanileko si tun menu ba awon idajo ti o n be fun awon irun odun mejeeji ti odun ba bo si ojo Jimoh.6- Alaye wa ninu apa kefa yi lori: (1) Nafila eyin irun Jimoh ati iye onka rakaa re. (2) Iwe fun irun Jimoh, se oranyan ni tabi kiise oranyan. (3) Awon ibeere lori oro Jimoh ati gbogbo ohun ti o ropo mo o pelu idahun lori won.

Artist

Sharafuddeen Gbadebọ Raji

Category

Islam, Podcasts, Religion & Spirituality, Education
Untitled
Unknown
00:00 / 00:00